Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìtàn àti Bíbélì

Àkọsílẹ̀ bí wọn ṣe pa Bíbélì mọ́, tí wọ́n túmọ̀ rẹ̀, tí wọ́n sì pín in kiri ṣàrà ọ̀tọ̀. Àwọn ohun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ń rí báyìí túbọ̀ fi hàn pé òótọ́ láwọn ìtàn tó wà nínú Bíbélì. Láìka ẹ̀sìn tí ò ń ṣe sí, wàá rí i pé Bíbélì yàtọ̀ sí ìwé èyíkéyìí mìíràn.

ÀWỌN ÌṢẸ̀LẸ̀ GIDI

Wọ́n Mọyì Bíbélì​—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale

Àwọn iṣẹ́ tó ṣe fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Bíbélì, a sì ń jàǹfààní látinú ẹ̀ títí dòní.

ÀWỌN ÌṢẸ̀LẸ̀ GIDI

Wọ́n Mọyì Bíbélì​—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale

Àwọn iṣẹ́ tó ṣe fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Bíbélì, a sì ń jàǹfààní látinú ẹ̀ títí dòní.

Ìtẹ̀jáde

Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?

Kí ni lájorí ẹ̀kọ́ tá a lè kọ́ nínú Bíbélì?