Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọdún 1914 Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso

Ọdún 1914 Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso

Wo fídíò yìí kó o lè rí bí àsọtẹ́lẹ̀ tó wà nínú Bíbélì ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé ọdún 1914 ni “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn” bẹ̀rẹ̀ àti pé ọdún yẹn náà ni Ìjọba Ọlọ́run bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso lọ́run.—2 Timothy 3:1.