JÍ! May 2013 | Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere

Ọ̀pọ̀ bàbá ló ti rí i pé àwọn ìlànà Bíbélì ń ran àwọn àti ìdílé àwọn lọ́wọ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere

Ṣàyẹ̀wò àwọn ìlànà Bíbélì márùn-ún tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè jẹ́ bàbá rere.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bí Ọkọ Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Lílu Ìyàwó Rẹ̀

Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn tó ń hùwà ipa lọ́wọ́ láti yí ìwà wọn pa da?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bí Ẹ Ṣe Lè Yẹra Fún Sísọ Ọ̀rọ̀ Líle Síra Yín

Kí lo lè ṣe tí ọ̀rọ̀ líle bá ti nípa lórí àjọṣe àárín ìwọ àti ẹnìkejì rẹ?

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Fà Sí Ìṣekúṣe

Tó o bá fẹ́ mú inú Ọlọ́run dùn, ṣàyẹ̀wo ojú tí Ọlọ́run fi ń wò ohun tó ń mú ọkàn fà sí ìṣekúṣe?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bó O Ṣe Lè Máa Fi Òfin Lélẹ̀ Fún Ọmọ Rẹ Tó Ti Ń Bàlágà

Kí lo lè ṣe tí ọmọ rẹ bá sọ pé òfin rẹ ti le jù

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Ní Àìsàn Tó Ò Ń Bá Fínra? (Apá 1)

Àwọn ọ̀dọ́ mẹ́rin sọ ohun tó ń jẹ́ kí wọ́n lè máa fara da àìsàn tó ń ṣe wọ́n, kínú wọn sì máa dùn.