Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2018-2019​—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Máa Bá Wa Ṣe

Wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àyíká yìí, a máa gbọ́ àsọyé látẹnu aṣojú ẹ̀ka ọ́fí ìsì.

Jẹ́ Alágbára!

Ìpàdé yìí máa jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè ní okun táá jẹ́ ká lè dúró gbọin nínú ìgbàgbọ́.

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nígbà tí àpéjọ náà bá ń lọ lọ́wọ́.