Kíka Bíbélì àti Kíkẹ́kọ̀ọ́ Rẹ̀
Bíbélì Kíkà
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ka Bíbélì?
Báwo lọ̀pọ̀ èèyàn ti ṣe jàǹfààní látinú kíka Bíbélì?
Ètò Kíka Bíbélì
Ìbáà jẹ́ ètò Bíbélì kíkà ojoojúmọ́ lò ń wá tàbí ti ọdọọdún tàbí èyí tó wà fẹ́ni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ máa ka Bíbélì, ètò Bíbélì kíkà yìí máa wúlò fún ẹ.
Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá Kìíní: Wo Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì
Tó bá ṣẹlẹ̀ pé o rí àpótí ìṣura ńlá kan, ó dájú pé ó máa wù ẹ́ láti mọ nǹkan tó wà nínú ẹ̀? Bíbélì ò yàtọ̀ sí àpótí ìṣura. Àwọn ìṣura ọgbọ́n tó pọ̀ gan-an tó sì wúlò ló wà nínú ẹ̀.
Báwo ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá Kejì: Jẹ́ Kí Bíbélì Gbádùn Mọ́ Ẹ
Ohun márun-un tó máa jé kó o rí ara ẹ nínú Bíbélì kíkà rẹ.
Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá 3: Túbọ̀ Jàǹfààní Púpọ̀ Bó o Ṣe Ń Ka Bíbélì
Ohun mẹ́rin tó o lè ṣe kó o lè túbọ̀ jàǹfààní púpọ̀ bó o ṣe ń ka Bíbélì.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
Ki Nidi To Fi Ye Ko O Kekoo Bibeli?
Nje o ti ronu ri pe, ‘Mi o ki i raye,’ tabi ‘Mi o feran ki n maa sadehun’?
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Lóye Bíbélì?
Ọ̀p gbà pé ọba ìwé ni Bíbélì láìmọ bí wọ́n ṣe lè jàǹfààní nínú rẹ̀.
Kí Ló Yẹ Kí O Ṣe Kó O Lè Lóye Bíbélì?
O lè lóye ọ̀rọ̀ pàtàkì tó wà nínú ẹ̀.