Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Àwọn Ẹ̀dá Ẹ̀mí​—Ohun Tí Wọ́n Ń Ṣe fún Wa (Apá 1)

Orí kẹwàá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Ṣe àyẹ̀wò ohun tí Bíbélì fi kọ́ni nípa àwọn áńgẹ́lì. Wo ohun tó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì tó jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run àti àwọn tí kì í ṣe olóòótọ́.