Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ẹ̀kọ́ 40: Jèhófà Máa Ń Dárí Jini

Ẹ̀kọ́ 40: Jèhófà Máa Ń Dárí Jini

Tá a bá ṣe nǹkan tí ò dáa, kí la lè ṣe tí Jèhófà á ṣì fi máa jẹ́ ọ̀rẹ́ wa?

 

O Tún Lè Wo

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Àwòrán Gàdàgbà: Jèhófà Máa Ń Dárí Jini

Àwòrán yìí rán wa létí bí Jèhófà ṣe máa ń dárí ji àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́ tí wọ́n bá ṣàṣìṣe. Wà á jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́.

ÀWỌN FÍDÍÒ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà

Kẹ́kọ̀ọ́ lára àwọn ọ̀rẹ́ Jèhófà tí Bíbélì sọ̀rọ̀ wọn!

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.