Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ẹ̀kọ́ 16: Máa Wàásù fún Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Míì

Ẹ̀kọ́ 16: Máa Wàásù fún Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Míì

Kọ́ nípa bí Kọ́lá àti Tósìn ṣe wàásù fún ẹnì kan tí kò gbọ́ èdè wọn.

O Tún Lè Wo

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Máa Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Language Kó O Lè Wàásù fún Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Míì!

Kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ kéékèèké ní èdè míì kó o lè ran àwọn míì lọ́wọ́ láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Jèhófà.

ÀWỌN FÍDÍÒ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà

Kẹ́kọ̀ọ́ lára àwọn ọ̀rẹ́ Jèhófà tí Bíbélì sọ̀rọ̀ wọn!

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.