Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Guatemala

Ìsọfúnni Ṣókí—Guatemala

  • 18,918,000—Iye àwọn èèyàn
  • 39,022—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 825—Iye àwọn ìjọ
  • 488—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Fìfẹ́ Hàn sí Wọn Gan-an

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ṣe Tán Láti Bẹ̀rẹ̀ Àtúnṣe Sáwọn Ilé Tí Ìmìtìtì Ilẹ̀ Bà jẹ́ ní Guatemala àti Mexico

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìrànwọ́ láti ṣèrànwọ́ fáwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin tí ìmìtìtì ilẹ̀ méjì tó wáyé ba ilé wọn jẹ́ ní Mexico àti Guatemala.