Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Philippines

  • Manila, Philippines​—Wọ́n ń sọ ohun tó wà nínú Bíbélì fún àwọn èèyàn ní àgbègbè Intramuros

  • Baler, Agbègbè Aurora, Philippines​—Wọ́n ń pé àwọn tó ń gbé ibẹ̀ wá sí ìpàdé

  • Manila, Philippines​—Wọ́n ń sọ ohun tó wà nínú Bíbélì fún àwọn èèyàn ní àgbègbè Intramuros

  • Baler, Agbègbè Aurora, Philippines​—Wọ́n ń pé àwọn tó ń gbé ibẹ̀ wá sí ìpàdé

Ìsọfúnni Ṣókí—Philippines

  • 113,964,000—Iye àwọn èèyàn
  • 253,876—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 3,552—Iye àwọn ìjọ
  • 464—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Mo Di “Ohun Gbogbo fún Ènìyàn Gbogbo”

Àwọn iṣẹ́ tí Denton Hopkinson ti ṣe nínú ìjọsìn Jèhófà látọdún yìí wá ti jẹ́ kó rí bí Jèhófà ṣe ń fa àwọn èèyàn láti ibi gbogbo sínú ètò rẹ̀.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú ní Philippines.

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó mú kí àwọn kan fi iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe sílẹ̀, kí wọ́n ta àwọn ohun ìní wọn, tí wọ́n sì lọ sí àdádó ní orílẹ̀-èdè Philippines