Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

May 30–June 5

2 SÁMÚẸ́LÌ 7-8

May 30–June 5
  • Orin 22 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jèhófà Bá Dáfídì Dá Májẹ̀mú”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Sa 8:2​—Àsọtẹ́lẹ̀ wo ló ṣẹ nígbà tí Dáfídì ṣẹ́gun àwọn ọmọ Móábù? (it-2 206 ¶2)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 7:1-17 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI