Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Àwọn Míì

Bó O Ṣe Lè Ní Ọ̀rẹ́

Ìdílé Aláyọ̀ àti Ọ̀rẹ́ Àtàtà Lè Mú Káyé Ẹni Dáa Sí I

Tó o bá fẹ́ ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú àwọn mí ì, ńṣe ni kó o máa ṣoore fáwọn èèyàn dípò kó máa retí pé kí wọ́n máa ṣoore fúnẹ.

Ta Ni Ọ̀rẹ́ Tòótọ́?

Kò ṣòro rárá láti ní ọ̀rẹ́ burúkú, àmọ́ báwo ni o ṣe lè rí ọ̀rẹ́ tòótọ́

Ṣó Yẹ Kí N Mú Àwọn Míì Lọ́rẹ̀ẹ́ Yàtọ̀ Sáwọn Tá A Ti Jọ Ń Ṣọ̀rẹ́?

Tó o bá wà láàárín àwọn pàtó kan tẹ́ ẹ ti jọ ń ṣọ̀rẹ́, ó lè mára tù ẹ́, àmọ́ kì í fìgbà gbogbo ṣàǹfààní. Kí nìdí?

Téèyàn Bá Dá Wà

Ohun To O Le Se To Ba N Se E Bi I Pe O Ko Ni Ore

Ti inu re ba n baje tori pe o ko loree, nse lo maa n da aisan si e lara, o maa dabi eni to n mu siga meedogun lojumo. Ki lo le se ko ma baa maa se e bi i pe won pa e ti tabi pe o ko loree?

Kí Nìdí Tí Mi Ò Fi Ní Ọ̀rẹ́ Kankan?

Kì í ṣe ìwọ nìkan ló máa ń ṣe bíi pé ó dá wà tàbí pé kò ní ọ̀rẹ́. Kà nípa bí àwọn ẹgbẹ́ rẹ ṣe borí èrò yìí.

Kí Nìdí Táwọn Ẹgbẹ́ Mi Ò Fi Gba Tèmi?

Èwo ló dáa jù nínú káwọn tíwà wọn ò dáa gba tìẹ àti pé kó o jẹ́ káwọn èèyàn mọ irú ẹni tó o jẹ́ gan an?

Ayélujára

Fi Iṣẹ́ Sílẹ̀ “Síbi Iṣẹ́”

Àbá márùn-ún tí kò ní jẹ́ kí iṣẹ́ ṣèdíwọ́ fún ìgbéyàwó rẹ.

Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Ẹ̀rọ Ìgbàlódé Gbà Ẹ́ Lọ́kàn

Bó o ṣe ń lo ẹ̀rọ ìgbàlódé lè ṣe ìgbéyàwó rẹ láǹfààní tàbí kó ṣàkóbá fún un. Kí ló ń ṣe fún ìgbéyàwó rẹ?

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Gbígbé Fọ́tò Sórí Ìkànnì?

Tó o bá ń gbé fọ́tò ẹ sórí ìkànnì, àwọn ọ̀rẹ́ àtàwọn ẹbí ẹ lè rí i, á sì rọrùn láti máa kàn síra yín, àmọ́ ó tún léwu.

Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò

Máa ṣọ́ra fún ewu lórí ìkànnì tó o bá ń bá àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ṣeré níbẹ̀.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?

Ọ̀rọ tó o fi ránṣẹ́ lórí fóònù lè ba àjọṣe tó o ní pẹ̀lú àwọn míì jẹ́, ó sì lè bà ẹ́ lórúkọ̀ jẹ́. Kà bó ṣe lè ṣẹlẹ̀.

Fífẹ́ra Sọ́nà

Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?

Ohun márùn-ún tó máa jẹ́ kó o mọ̀ bóyá o ti ṣe tán láti lẹ́ni tí wàá máa fẹ́, tó o sì lè bá ṣègbéyàwó.

Ṣé Ó Burú Kéèyàn Máa Tage?

Kí ló túmọ̀ sí gan-an kéèyàn máa tage? Kí ló máa ń mú káwọn kan ṣe bẹ́ẹ̀? Ṣé ó tiẹ̀ léwu?

Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán Ni Wá àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́?—Apá 1: Báwo Ni Ẹni Yìí Ṣe Ń Ṣe sí Mi?

Wo àwọn ohun tó o lè ṣe kó o lè mọ̀ bóyá bí ẹnì kan ṣe ń ṣe sí ẹ fi hàn pé ó fẹ́ kẹ́ ẹ máa fẹ́ra àbí ó kàn fẹ́ kẹ́ ẹ jẹ́ ọ̀rẹ́.

Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán Ni Wá àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́?—Apá 2: Báwo Ní Mo Ṣe Ń Ṣe sí Ẹni Yìí?

Ṣé kì í ṣe pé ọ̀rẹ́ rẹ ti ń wò ó pé o fẹ́ kí ẹ máa fẹ́ra? Wo àwọn àbá yìí.

Ṣé Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni àbí Ìfẹ́ Ojú Lásán?

Mọ ìyàtọ̀ tó wà láàárín ìfẹ́ ojú lásán àti ìfẹ́ tòótọ́.

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Gbígbé Pọ̀ Láìṣègbéyàwó?

Àwọn ìtọ́ni Ọlọ́run jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè ní ìdílé aláyọ̀, kò sì ìgbà tí ìlànà rẹ̀ kì í ṣe àwọn tó bá ń tẹ̀ lé e láǹfààní.

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Òfin tí Wọ́n Máa Ń Tẹ̀ Lé tí Wọ́n Bá Ń Fẹ́ra Sọ́nà?

Ṣe eré ìnàjú lásán làwọn tó ń fẹ́ra sọ́nà ń bára wọn ṣe àbí ó jù bẹ́ẹ̀ lọ?

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Ìlànà Bíbélì lè ràn wá lọ́wọ́ láti yan ọkọ tàbí aya rere, ó sì lè jẹ́ kí tọkọtaya máa fìfẹ́ tòótọ́ hàn sí ara wọn.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ̀dùn Ọkàn Tá Ò Bá Fẹ́ra Wa Mọ́?

Wo bó o ṣe lè bọ́ lọ́wọ́ ẹ̀dùn ọkàn tó lágbára.

Bá A Ṣe Lè Yanjú Àìgbọ́ra-ẹni-yé

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Tọrọ Àforíjì?

Wo ìdí mẹ́ta tó fi dáa kó o sọ pé ‘Máà bínú,’ tó o bá tiẹ̀ rò pé ọwọ́ ẹ kọ́ ni gbogbo ẹ̀bi wà.

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìbínú?

Ṣé ó tọ́ kéèyàn bínú rárá? Kí ló yẹ kó o ṣe tí ìbínú ẹ bá ti ń le?

Kí Ni Ìdáríjì?

Bíbélì sọ ohun márùn-ún tó lè ràn ẹ lọ́wọ́ láti dárí ji ẹni tó ṣẹ̀ ọ́.

Bí Ẹ Ṣe Lè Máa Dárí Ji Ara Yín

Kí nìdí tó fi lè ṣòro fún wa láti dárí jini? Wo bí àwọn ìmọ̀ràn inú Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́.

Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀​—⁠Ìdáríjì

Tí ìgbésí ayé ẹni bá kún fún ìbínú ní gbogbo ọjọ́, téèyàn sì ń gbé ọ̀rọ̀ sọ́kàn, èèyàn ò ní láyọ̀, ìlera rẹ̀ ò sì ní dára.

Prejudice and Discrimination

Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti Ní Ẹ̀tanú?

Ọjọ́ pẹ́ táwọn èèyàn ti ń ṣe ẹ̀tanú sí àwọn míì. Bíbélì sọ ohun tá a lè ṣe tá ò fi ní fàyè gba ẹ̀mí burúkú yìí nínú ọkàn wa.

Ìwà Ẹ̀tanú​—Ìṣòro Tó Kárí Ayé

Kí ni ẹ̀tanú? Kí nìdí tí a fi gbà pé kárí ayé ni ẹ̀tanú ń bá àwọn èèyàn fínra lẹ́nì kọ̀ọ̀kan?

Ṣé O Ní Ìkórìíra?

Àwọn ìwà àti ìṣe wo ló lè fi hàn pé a ní ẹ̀tanú tàbí ìkórìíra?

Bíbélì Lè Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Máa Bọ̀wọ̀ fún Èrò Àwọn Míì

Àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká rí i pé Bíbélì fẹ́ ká wà ní àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn ká sì máa bọ̀wọ̀ fún wọn.

Ohun Tó Lè Fòpin Sí Ìkórìíra​—Yẹra fún Ojúsàájú

Ó lè borí èrò tí ò dáa tó o ní sáwọn èèyàn tó o bá fara wé Ọlọ́run tí kì í ṣe ojúsàájú.

Ìkórìíra​—Yan Onírúurú Èèyàn Lọ́rẹ̀ẹ́

Wo àǹfààní tó o máa rí tó o bá ń bá àwọn mí ì sọ̀rẹ́ yàtọ̀ sáwọn tó o gbà pé ẹ ti mọwọ́ ara yín.

Ṣé Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Táwọn Èèyàn Ò Ní Máa Gbé Ẹ̀yà Kan Ga Ju Ẹ̀yà Míì Lọ?​—Kí Ni Bíbélì Sọ?

Bíbélì ti jẹ́ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn mọ bí wọ́n ṣe lè máa bọ̀wọ̀ fáwọn míì, kí wọ́n sì máa pọ́n wọn lé.

Ìgbà Wo Ni Ayé Yìí Máa Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ̀tanú?

Ìrírí àwọn tó jẹ́ ká mọ̀ pé Bíbélì ń ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè borí ẹ̀tanú. Ìgbà wo ló máa dópin pátápátá?

Ìgbà Wo Ni Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Máa Ṣẹ́gun Ìkórìíra?

Kò rọrùn láti fa ẹ̀tanú tu kúrò lọ́kàn. Wo bí Júù kan àti ará Palẹ́sínì kan ṣe ṣàṣeyọrí.

Johny àti Gideon: Ọ̀tá Ni Wọ́n Tẹ́lẹ̀, Wọ́n Ti Di Arákùnrin Báyìí

Láwọn ilẹ̀ kan, kò sí ibi tó o yíjú sí tí o kò ti ní rí ìwà kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà lójoojúmọ́. Wo bí àwọn ọkùnrin méjì tí wọ́n ń gbé ní South Africa ṣe borí ìṣòro yìí.

Mo Fẹ́ Jà fún Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn

Rafika wọ ẹgbẹ́ ajàfẹ́ẹ̀tọ́-ọmọnìyàn kó lè gbógun ti ìwà ìrẹ́jẹ. Àmọ́, ó wá kọ́ nípa ìlérí tó wà nínú Bíbélì nípa àlááfíà àti ìdájọ́ òdodo lábẹ́ Ìjọba Ọlọ́run.